Yoruba Expository of Ajaagbeejo

ìtan ÀJAGbééjò (story of ajagbe ejo)
AJAGbééjò jẹ́ ikan lara awọn ohun àrà tí ÓLODUMARE da sí inú ìbú.
̣ọdẹ toba gbọwọ tabi apẹja toba gbọwọ nikan lolé de ibi ti ajagbééjo wa.
BÁWO NI AJAGBÉÉJO SÉÉRÍ ?
ÁJÁGBÉÉJO jẹ ẹjá toda bí éjò , oo ní ìpẹ lára bí tí éjò sugbọn oorí ẹja loni.
owa lákọ pẹlu abo. The female is bigger than the the male. 
IWÙLO ÁJÁGBÉÉJO
wọn máá nlo ájágbééjo fún orísirísi íse
wọn máá nlo fún awọn toju ọmọ npán
wọn máá nlo fun awọn to nwá ọna abáyọ
wọn máá nlo fun awọn tó nwá owóó ati bẹ bẹ lọ
wọn máá njẹ bẹẹni wọn si maa njẹ ipẹ́ ẹ
BÁÁWO NÍ MOSÉÉ MỌ NÍPÁ ÁJÁGBÉÉJO ?
ORÍSÀ AJÉ OLOKÙN LO MÚ mi ririn ajò yi toosi fi iran naa han mi.
ÁJE OLOKUN ASỌ AGBA DÉWE
AJE OLOKUN ASỌ EWÉ DAGBA
OGUGU LÚSỌ
TI TẸRU TỌMỌ NFOJO JUMỌ WÁ KÍRÍ
AJÉ OLOKUN ASỌRỌ DÁYỌ
AJÉ ÍWỌ LÁ NJÍ KÍ, IWỌ LA NJI RÍ,
 ÍWỌ LÁ NJÍ KẸ́, IWỌ LÁÁ NJÍ PÉ
IWỌ LÁBỌMỌ TÍ NBORI AYÉ
IWỌ LÁ NMÚ SOKÚN, IWỌ LÁ NMÚ SEKÉ
IWỌ NI ANÍRỌPO , Ọ́BÁ TÍ NKO NA YANRÀN YANRÀN, YANRÀN 
ÁJÉ O, AGBA ORISA JẸ KÍN NI LỌWỌ
MÁ JẸ KI N NI Ẹ LỌRUN
AJE WA FILE MI SE IBU GBÉ OOOO (ÁMÌN)
It’s not an ORISA to be worshipped, thanks to AJE OloKun for insight and knowledge. 
These are no Ajaagbeejo. But just for sight seeing. 
Fish that have snake head are called Ajagba Eja while a snake that has fish head is Ajaagbeejo. 
Ajaagbeejo has Scales on the body. 
Please not the differences.
For reading Sake to have an Idea, just google search for these topics below. 
Fish that look like snakes are:
1. Snake Eel,
2. Swamp Eel,
3. Fire Eel,
4. Snakehead,
5. Bichir,
6. Zebra Moray,
7. Lamprey,
8. Pipefish,
9. Violet Goby,
10. Kuhli Loach,
11. Reedfish / Ropefish,
12. Eelpout,
13. Hagfish, and
14. Lungfish.
ORÚKỌ MI KOYÍ PADA
ẸMÍ OOSÁ.(Odewole Olusegun). 

Source of Article: https://www.orisa.com.ng

AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733

This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.

You can contact AJE NLA for ...

ODU OBATALA Consultation

Egbe Orun INITIATION

OSUN Initiation

Begging of the elders

Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.


Discover more from ORISA BLOG

Subscribe to get the latest posts sent to your email.

By AJE NLA

Leave a Reply

Translate »