no fucking license
Bookmark

oriki OSOGBO OROKI

OSOGBO OROKI


Osogbo oroki asala omo onile obi osogbo ilu aro,

omo aro dede bi okun aare o peta arepeta mogba o,


osun osogbo pele o,

epele o eyin olomoyoyo osgbo oroki gbe onile,


otun gbe ajoji osogbo oroki,


osogbo oroki omo yeye osun yeye atewogbeja,


aniyun labebe oroki ti eja nla soro, 


ti ran iko nise osun osogbo, 


rere ni osun fun mi oroki onile obi,


alaro omo asala EDUMARE BAWA DA ILU OSOSGBO SI ASE

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.

Post a Comment

Post a Comment