ORÍKÌ SÀǸGÓ
Ṣàǹgó Olúkòso
Àyàrán iná, akata yerí yerì
Arábámbí Ọkọ Ọya
Olójú Orogbó, Ẹlẹ́rẹ̀kẹ́ òbí
Iná lójú, iná lénu
Arigba ota ségun
Eégún tin yo ina lénu
Sàngó ma bami ja
Sàngó bá wa ségun ọ̀tá o
Sàngó, the king of Koso town
One who blows lights and flames here and there
Arábámbí, the husband of Ọya
One that has eyes of bitterkola and cheeks full of Kolanut.
One who splits fire from the eyes and mouth
One who uses 200 thunderstones to defeat his enemies
The masquerade that splits fire from the mouth
Sàngó don't fight/quarrel with me
Sàngó help us to defeat our enemies
Sango, use your 200 thunderstones to fight for us today so we have the victory over our enemies.... Àṣẹ!
Kabiesi Sango!
Kabiesi Sàngó!!
Kabiesi Sango O!!!!!
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment