Month: June 2023

ODU ÒTÚRÚPỌ̀N ÌROSÙN

ÒTÚRÚPỌ̀N ÌROSÙN: Ìtàn àmọ̀jù níí m’ẹ́yẹ oko ó sùn’gbẹ́ Díá fún Àdàbà súùsúù Tí ńlọọ́ bú ará Ìṣokùn l’ẹ́rú Ẹbọ ni wọ́n ní kí wọ́n wá ṣe Wọ́n kọ’tí ọ̀gbọnyìn…

Translate »