Ajé, olókun ògúgúlúsọ̀,
Ajé, oníre,
Asọ̀rọ̀dayọ̀
Ajé, onísọ̀ bòòji,
Ajé, asọèwedàgbà,
Ajé, asọàgbàdèwe,
Ajé, àjíkí,
Ajé, àjíkẹ́,
Ajé, àjípè,
Ajé, wá fi ilé mi ṣe ibùgbé,
Àgbà òrìṣà, jẹ́ kí n ní o lọ́wọ́,
Má jẹ̀ẹ́ n ní o lọ́rùn.
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
1 comment