EGBA ANTHEM / EGBA SONG
Lori oke o’un petele
Ibe l’agbe bi mi o
Ibe l’agbe to mi d’agba oo
Ile ominira
Chorus: Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo; Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo
Abeokuta ilu Egba
N ko ni gbagbe e re
N o gbe o l’eke okan mi
Bii ilu odo oya
Emi o f’Abeokuta sogo
N o duro l’ori Olumo
Maayo l’oruko Egba ooo
Emi omoo Lisabi
E e
Chorus: Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo; Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo
Emi o maayo l’ori Olumo
Emi o s’ogoo yi l’okan mi
Wipe ilu olokiki o
L’awa Egba n gbe
Chorus: Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo; Maa yo, maa yo, maa yo o; l’Ori Olumo
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment