IWORI AYOKA
A n beere ibi oja gbe ta
Bee ni a o beere lowo Ori
Adifafun yimi yimi
Yoo mo sowo Ose
Adifafun Alantakun
Yoo mo sowo Owu
Adifafun Alabahun Ajapa
Yoo mo sowo Eree
Ebo ni won ni ki won o se
Won gbebo nibe won rubo
Nje a kii fi Ose yimi yimi foso
A kii fi Owu Alantakun ranso
Enikan kii je owe Alabahun
N se ni a n beere ibi oja gbe ta
Bee ni a o beere lowo Ori
Ifa ni bi ori bakun alabe lakesi bi odo bakun onutuko lape ountuko tete tumi ti obatete tumi emi ositurami adifafun iwori ayoka eyi tiwon ni koni okun omo ninu mon eebo ni awo nikose inje aromo gbomo pon niti Aya awo ari omo gbe omo pon niti seseki ari omo gbe omo pon niti Aya awo
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment