no fucking license
Bookmark

ODU IFA Iwori ika

OO       OO 
 O          O
OO         O
OO       OO


Ìnínírín l'Awo Ìnínírin


Ininirin l'Awo Ìnínìrìn


A difa fun Ajítobì


Tii s'Awo Iwori Ayoka


Won ni ko rubo


O gbe'bo O ru'bo


Nigba to ya


Bi won ba n bere obi


Won a ni e niso nile Ajitobi


Ajítobì wa d'eni olà


Awo kere, Awo dagba


Awo to dara la n b'obi nile e


Awo kere, Awo dagba


Awo to gboFa lan bobi nile e


Ajítobì aya Iwori Ayoka.



Iwori Ayoka (Iwori ika) as follows :-


K'oko o gbo k'aya o gbo nbe nibo mi

A bewu sese a moo s'oko ara won

Adifa fun Iwori ti yoo s'oko Ika d'ale

T'oba bini nbe aya 're ni nfe f'awo



Translation 


Let the husband live long with his wife

Couple with grey hairs marry each other

Cast divination for Iwori who will marry Ika with no end.

You are endowed with a good wife if this Odu appears for you.

May you live long with your Apetebi. Ase.




This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.

Post a Comment

Post a Comment