Ọlọ́wọ́gbọgbọrọ…
Ọlọ́wọ́gbọgbọrọ ni orúkọ tí à ń pe àwọn ìyàmi.
Ìbà àwọn ìyàmi ọlọ́wọ́gbọgbọrọ tí ńgba ọmọ wọn nínú ọ̀fìn ọmọ aráyé
Mo júbà àwọn ìyàmi ẹlẹ́yẹ Òṣòròngà
A ró igba aṣọ má’kanlẹ̀
Ọ̀pàké-Ọ̀làké
A ké ruru, a là ruru
Ají-ginni,
Arìn-ginni Arìn-gìnnì-ginnì wọ'jà
Tí kìí jẹ́ kẹ́’rù o b' ọmọdé títí d’ọjọ́ alẹ́ Ẹlẹ́yẹ,
a’bẹnu ródóródó Àtíòro balẹ̀ ṣẹ̀gẹ̀ṣẹ̀gẹ̀ Apanimáyọdà,
olókìkí òru
Afínjú ẹyẹ tí ń jẹ láàrín òru
A t'inú jẹ orí
A t'ẹ̀dọ̀ jẹ ọkàn
A t'ìfun jẹ òróòró
Ọ̀gàlàntà,
a j'ẹran ògún
A j'ẹ̀dọ̀ ènìyàn mọ 'yì
Ọlọ́jàá gbọ̀ọ̀rọ̀-gbọọrọ
Igúnnugún bá lé òrùlé
Ojú tó ilé Ojú tó oko
Ìbà o,
kí ìbà ṣẹ.
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment