ORIKI EGBA
Egba mo’lisa
Omo gbongbo akala
Omo erin jogun ola
Omo osi’lekun pa’lekun de
Aridi ogo loju Ogun Baba t’emi la royin ogun baara fagbe
Ko sohun ti won n se ni mecca
T’awa kii se Legba Alake
Won n mumi semi semi ni Mecca
Awa n mumi Odo Ogun legba Alake
Won n g’Arafa ni Mecca Awa n gori Olumo l’egba tiwa
Won bimi L’ake
Mo gbo lenu bi jeje
Won bimi ni Gbagura
Mo gbo lohun bi oje.
Edumare bawa da ilu Egba si
Ase
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment