ORIKI ILARO
ORIKI ILARO
Eji ogogo omo iku lodo toti deri’lewa
Omo adiye sun won sebi kuku loku, kiwon 
to lotatan adiye dide oyan fanda
Ilaro omo erin lonibu omo efon lo nona
Omo pakan lakan leyin jijo awo ni gbori ile 
omo ina tin jo geregere lori omi
Ilaro omo aran o sunwon e ko nigbale omo 
oku eko omo ijagudu akara
Ogogo omo e ba oro omo ina esan ogbo jinijinji ama jo’le gerege
Ogogo tin yini lokun lapa omo oku dudu ti koya kunran
Omo kulodo to tideri’lewa omo kinikan o joye lesa, tobawa joye lesa nko ilesanmi lasan loba yin muwon je.
Ogogo lomo agbele jebu, omo yiyo lanyo nile baba tobiyin lomo
Ilaro omo ku la ngberi omo kulodo ao ki wan kuloko tan won di apon
Otojo kotojo tomo kulodo nbo lati oko egan loba pade omi sonte, egbon mu 
aburo na mu gbogbo eni tomu sonte lomu rogbo dan

Source of Article: https://www.orisa.com.ng

AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733

This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.

You can contact AJE NLA for ...

ODU OBATALA Consultation

Egbe Orun INITIATION

OSUN Initiation

Begging of the elders

Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.


Discover more from ORISA BLOG

Subscribe to get the latest posts sent to your email.

By AJE NLA

Leave a Reply

Translate »