no fucking license
Bookmark

Oriki Ogbomoso, Oriki ilu Ogbomoso

ORIKI OGBOMOSO



Ogbomoso omo ajilete nbi won gbe n jeka ki won oto muko yangan


ogbomoso afogbo ja bi esu odara. 

Ngba ogbomoso ba se o n ti o se tan
Bo logbon inu osebi ere ni omo ajileten ba olu ware se ni. 


Ogun o jaja ki o kogbomoso ri e de inu oko esinmin


Ogbomoso Ajilete si ogo re l'a fe korin,

 Iwo t'a te s'arin odan, Okan ninu ilu Akin



Ibaruba niwon eledin ese, omo ode bare eti oya


Oun ni baba to se gbogbo won le patapata porogodo


Kekere asa omo ajuuju bala


Agbalagba asa omo ajuuju bala


Kekere ladaba subu tawon ti n je laarin ota
Oloumi kekke lo ti n soko won nile


Kekere lo ti n soko won lóki


Kekere lojo ti n soko won lona iju

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.

Post a Comment

Post a Comment