ORO AYALO NINU EDE YORUBA
Oro
ayalo (oro- ti- a- ya lo) ni oro ti a ya lati inu ede kan wo inu ede miiran ni
ona ti pipe ati kiko re yoo fi wa ni lbanu pelu batani iro ede ti a ya a wo.
A
n ya oro lati sapejuwe asa tuntun ti a n ba pade ni pase owo, iselu, imo ero,
imo sayensi, esin, eti amuluudun laarin awon ti n so ede kana ti elede miiran. Ni Pataki oro ayalo maa n je ki ede kun si.
inu awon ede ti yoruba ti ya ede lo
ni :
EDE |
APEERE ORO TI A YA WO |
Geesi |
Buredi, Fulawa, |
HAUSA |
Wahala, alafia, |
Faranse |
Sinmi, taba, abbl |
Larubawa |
Alubarika, Alubosa |
Inu edeGeesi ni Yoruba lati ya oro julo, idi abojo ni wi pe.
(i)
ajosepo ojo pipe ti wa
laarin ijoba Geesi ati ile naijiria
(ii)
ati pe ede Geesi lo tun
je ede ijoba orile- ede Naijiria tan ihun ede Yoruba ati oro ayalo
Awon
oro ti a ya wo inu ede Yoruba gbodo wa ni ibamu pelu batani bi a ti se n ko
awon ina ede Yoruba sile
Bi
apeere:
i)
Konsonanti ki pari
silebu tabi oro Yoruba
ii)
Isopo konsonanti ko
gbodo waye ninu silebu ede Yoruba
iii)
Gbogbo oro
ayalo ni a gbodo lo ami ohun si ni ori
iv)
Inu oro
ayalo gbodo tele ilana apele koofo: Kf tabi FKF
v)
Ohun oke
ko le bere oro yoruba onibatani F1 – KF2 ati pe
vi)
Faweli
aranmupe ko le je F1 ninu oro onibatani F1 – KF2
EDA ORO AYALO
Orisii ona
ti a le gba ya oro lati inu ede Geesi we inu ede yoruba ni yala nipa ilana
afetiya ati afojuya.
1.
ILANA
AFETIYA : – Eyi ni ki a tele ilana bi ase fie ti gbe bi oro ti dun tabi bi
awon elede se pee
Bi apeere :
Tailor – Telo
Bible – baibu
peter – pita
2.
ILANA AFOJUYA: – Oro
ayalo afojuya ni awon oro ti a ya nipa ti tele ilana bi awon elede ti a ti y a
won se n ko awon oro bee sile.
Bi apeere: –
Table – Tabili
Milk – miliki
Bible – Bibeli
Awon oro
Ayalo Kanwa ti won ni eda afeti ati afojuya
Bi apeere: –
ORO GEESI |
AFETIYA |
AFOJUYA |
Peter |
pita |
Peteru |
Contractor |
kongitato |
Kontiracto |
inspector |
Ripeto |
Ihinsipekito |
Esther |
Esita |
Esiteri |
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.