no fucking license
Bookmark

ORO AYALO NINU EDE YORUBA

ORO AYALO NINU EDE YORUBA




         Oro ayalo (oro- ti- a- ya lo) ni oro ti a ya lati inu ede kan wo inu ede miiran ni ona ti pipe ati kiko re yoo fi wa ni lbanu pelu batani iro ede ti a ya a wo.




         A n ya oro lati sapejuwe asa tuntun ti a n ba pade ni pase owo, iselu, imo ero, imo sayensi, esin, eti amuluudun laarin awon ti n so ede kana ti elede miiran. Ni Pataki oro ayalo maa n je ki ede kun si.





inu awon ede ti yoruba ti ya ede lo ni :

EDE

APEERE ORO TI A YA WO EDE YORUBA

Geesi

Buredi, Fulawa, sikeeti, sitoofu abbl

HAUSA

Wahala, alafia, mogaji, labara, ankali, abbl

Faranse

Sinmi, taba, abbl

Larubawa

Alubarika, Alubosa mogarubi, anjonu, mojesi, mekunu

 




Inu edeGeesi ni Yoruba lati ya oro julo, idi abojo ni wi pe.




(i) ajosepo ojo pipe ti wa laarin ijoba Geesi ati ile naijiria



(ii)        ati pe ede Geesi lo tun je ede ijoba orile- ede Naijiria tan ihun ede Yoruba ati oro ayalo



Awon oro ti a ya wo inu ede Yoruba gbodo wa ni ibamu pelu batani bi a ti se n ko awon ina ede Yoruba sile




Bi apeere:



i)    Konsonanti ki pari silebu tabi oro Yoruba



ii)  Isopo konsonanti ko gbodo waye ninu silebu ede Yoruba



iii)         Gbogbo oro ayalo ni a gbodo lo ami ohun si ni ori



iv)          Inu oro ayalo gbodo tele ilana apele koofo: Kf tabi FKF




v)   Ohun oke ko le bere oro yoruba onibatani F1 – KF2 ati pe



vi)          Faweli aranmupe ko le je F1 ninu oro onibatani F1 – KF2

 



EDA ORO AYALO


         Orisii ona ti a le gba ya oro lati inu ede Geesi we inu ede yoruba ni yala nipa ilana afetiya ati afojuya.



1.    ILANA AFETIYA : - Eyi ni ki a tele ilana bi ase fie ti gbe bi oro ti dun tabi bi awon elede se pee



Bi apeere :


Tailor – Telo

Bible – baibu

peter – pita




2.   ILANA AFOJUYA: - Oro ayalo afojuya ni awon oro ti a ya nipa ti tele ilana bi awon elede ti a ti y a won se n ko awon oro bee sile.




Bi apeere: - 

Table – Tabili

Milk – miliki

Bible – Bibeli




         Awon oro Ayalo Kanwa ti won ni eda afeti ati afojuya



Bi apeere: -



ORO GEESI

AFETIYA

AFOJUYA

Peter

pita

Peteru

Contractor

kongitato

Kontiracto

inspector

Ripeto

Ihinsipekito

Esther

Esita

Esiteri

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.

Post a Comment

Post a Comment