OWO
YIYA ATI ONA TI A FI N GBA GBESE

Owo yiya je lara
awon ona ti awon Yoruba gba ran ara won lowo ni atijo titi di ode –oni.

DIE NINU AWON
IDI TI A FI N YSA OWO LAYE ATIJO.

1.      Oku baba tabi iya eni sisin

2.     Oku ana sisin

3.     Ile kiko

4.     Iyawo fife

5.     Aisan wiwo

6.     Fifi tan oran

AWON ONA TI A N
GBA YAWO NI ATIJO

1.      Kiko owo ele

2.     Fifi nnkan duro tabi dogo

3.     Fifi omo kowo tabi sofa

DIE LARA AWON
OFIN TO DE IWOFA

1.      Abo ise ni ise iwofa

2.     Iwofa kii se eru nitori naa o ni omonira
tire

3.     Olowo ko gbodo ba iwofa obinrin lo, bi o
ba se bee, o gbodo sanwo itanran.

DIE AWON ONA TI
A N FI GBA GBESE LAYE ATIJO

1.      Sisin gbese funra olowo

2.     Didogo ti ajegbese ati fifooro emi re
titi ti yoo fi sanwo.

3.     Riran elemu-un lo si ile ajegbese .

ORISII ONA TI A
N GBA YAWO NI ODE-ONI.

1.      Owo yiya ni banki

2.     Lati inu Egbe Alafowosowopo

3.     Lati inu apo Egbe Alajo Dida

4.     Lowo Ajo ayanilowo sise tabi Ayanilowo
kole.   

Source of Article: https://www.orisa.com.ng

AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733

This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.

You can contact AJE NLA for ...

ODU OBATALA Consultation

Egbe Orun INITIATION

OSUN Initiation

Begging of the elders

Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.


Discover more from ORISA BLOG

Subscribe to get the latest posts sent to your email.

By AJE NLA

Leave a Reply

Translate »