Uses of Cat Eye (Iwulo Oju olongbo)

Iba agba o
Uses of Oju olongbo (cat eyes) 
Die Lara iwulo ESO oju olongbo,
1: Ifunra (body__Teller)
Ao mun ESO oju olongbo kan, ESO olonsepetu kan na, (opa_esu), omo Atare kan, Ao lo papo Ao fi singbere kan soso sii Aya…. 
2.. Eyonu {Favor}
ESO oju olongbo mesan 9
Omo Atare mesan 9, Ao lo papo Ao fii singbere EJIOGBE SII APA OSI NIKAN,  ODAJU
3, Afoibon (to break gun)
ESO oju olongbo 16, 
Omo Atare 16, Ao lo papo, Ao fi singbere yipo APA mejeji ,, ODAJU PA
4, Ayeta ibon TODAJU
ESO oju olongbo mesan 
ESO omo irula mesan
Oju eyele mejeji, 
Karahun igbin die, Ao lo papo Mon Ara won,, 
Ao fii singbere Ejiogbe Mesan sii Aya ati Eyin wa ..
5, OGUN IBON AGBEKORUN
ESO oju olongbo mesan
Omo Atare mesan
Arigisegi to wa ninu ile, 
Ao ko awon ESO yi sinu Iwo arigisegi na, Ao di ni ikobere … 
Ao GBE korun, 
Ao ma WO singlet tele aso wa, ao sese wa GBE korun, 
6, gbere ajeegun omo yahoo, 
Ao bo eepo inu ESO oju olongbo meta kuro ao wa lo yellow inu re Mon omo Atare meta, pelu eepo obo die, ao.lo kuna 
Ao fi singbere sii orikerike ara …  
ATUDE NII..

Source of Article: https://www.orisa.com.ng

This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA +2347031178647.

You can contact AJE NLA for ...

ODU OBATALA Consultation

Egbe Orun INITIATION

OSUN Initiation

Begging of the elders

Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.


Discover more from ORISA BLOG

Subscribe to get the latest posts sent to your email.

Leave a Reply

Translate »