no fucking license
Bookmark

Ìbà Ọ̀RÚNMÌLÀ (Orunmila Praise)

Ìbà Ọ̀RÚNMÌLÀ,

 Bara-Ẹlẹ́sínọyán 

 Ọkọ Ajé, O jí ire ló nì ín 


O jí ire ní Ìkọ-àhúsí 

O jí ire ní Ìdàhòmì-àhúsẹ̀ 

O jí ire ní Ìwọnràn-ọlà, 

ní ibi ojúmọ́ ire tí gbé mọ́ wá.  

Egúngún Olú-ufẹ̀ tí í sán mọ̀rìwọ̀ pàrìko 

A ò ba se, ẹ̀rù kò bà á 

Atóbá-jayé mọ́ jáyà lolo....... ........

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.

Post a Comment

Post a Comment