Oriki EGBE Orun Olugbogero

Oriki EGBE Orun Olugbogero
Below is the their oriki
Paaka inu abiku 
Eyin ni so ekun derin 
Eyin la soro dayo 
Olugbogero olore 
ito Onamonaya ti be nicer 
Timi Orisa ti Timi ko ri ti fi Ifà wa kiri
Olugbogero awele 
Ponpola abaso 
yepe yepe bi mo n re Ibadan 
nile Oluyole arosi ma Ja mi ju si ogunpa. 
Orisha to ti inu agbara jade Eni oluwa mi ba daso fun Iru won ni ma hun yora 
Translation
Paaka the one who is closely related to abiku 
You that turn weeping to laughter
 You that turns sadness to gladness 
Olugbogero the one with fierce cane 
One who flog mother and child that leaves in city of Timi Olugbogero awele 
Ponpola with flamboyant and myriad clothing 
If I get to Ibadan city the abode of Oluyole 
please don’t dump in Ogunpa river 
The deity that originate from muddy erosion whomever my lord give clothes
 He will be changing clothes the way he wants.

Source of Article: https://www.orisa.com.ng

This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA +2347031178647.

You can contact AJE NLA for ...

ODU OBATALA Consultation

Egbe Orun INITIATION

OSUN Initiation

Begging of the elders

Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.


Discover more from ORISA BLOG

Subscribe to get the latest posts sent to your email.

Leave a Reply

Translate »