ORiki Obatala (Orisanla)
Baala O!
Oro oo r’Elu 🪘🤍🐚🕊️🕊️
IGBIN 🪘ogbomo la
Igiin omo Akoro 🪘
Otu koko Ala fomo t’ ore
Osun-Sile-foje tikun
Onile- ji, Oje-O-ji!
Ogbagba tii fowo aala gbale
Irin kobo-kobo a fi n bowu
O gbaa giri da ‘nu I’owo osika
O fo osika I’oju afota
O Le odale ka’nu Owu bara-bara
Awoni-pepe bi eniti o ri’ni
Alapata okunrin asa’ran m’eegun
A’je Eku bi mirin
O’je Eja bi Igere
Akorin mu’tin
Ayena-j’obi 🐚🐚🐚
Afun’ ni mo t’ owo eni
Ofun Nini,gba fun Aini
O so enikan digba eni
Alase,oba afase s’ oro
Ibante funfun 🤍🤍
Sokoto funfun🕊️🕊️🕊️
O L’epo,Nile je ila funfun
Onile oju opo
Eleeta Iranje
Alade sesefun 🤍🕊️🕊️🕊️🕊️
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment