How we started learning Yoruba Alphabets in Primary School in those days. Only OG will remember 😀
Nje iwo ranti bi ?
A - Aja
B - Bata
D - Doje
E - Ejo
Ę- Ęye
F - Fila
G-gele
Gb-gbaguda
H-hausa
I-igi
J-jagunjagun
K-kiniun
L-labalaba
M-malu
N- Nagudu
O- Ògòǹgò
O- Ọ̀gẹ̀dẹ̀
P - Pepeye
R- Rankunmi
W - waala
Y - Yanmu Yanmu
Post a Comment