Okanran Ogunda
Eni owo nya fun ire ni Ogun igbee ojo ija
Eniyan ti ko le ja, ti ko le soro
ko nii le gbe ninu aye pe
Ija nsola; ija nse iyi
A difa Ogungbemi
Won ni bi ko tile nii finran
nigbakigba ti ija ba de sii
Ki o ma maa sa o
Alagbara ni o ni aye
Kosi eniti t’o je buyin fun ole
Akin ni o ni aye
won kii bu ola fun ojo
won niki o wa rubo
Ki iye inu ma ra ati ara lile
Translation 
One who stands ready to act for the good
is supported by Ogun on the day of battle,
A person who cannot fight or talk does not live long on earth
Struggle brings respect; struggle brings honor,
This was the teaching of Ifa for Ogungbemi,
They said that even if he does not provoke it,
Whenever the fight comes to him,
He should not run away from it.
It is the powerful who have control of the world
No one respects the passive person
It is the courageous who lay claim to the world, 
People do not give consideration to the coward
He was asked to sacrifice.
So that his internal strength would not perish
and his body would remain sound.

Source of Article: https://www.orisa.com.ng

AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733

This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.

You can contact AJE NLA for ...

ODU OBATALA Consultation

Egbe Orun INITIATION

OSUN Initiation

Begging of the elders

Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.


Discover more from ORISA BLOG

Subscribe to get the latest posts sent to your email.

By AJE NLA

Leave a Reply

Translate »