no fucking license
Bookmark

ODU IFA OSE MEJI.

Ọ́sẹ́ wómú

Ó rún wómú


Adifafun Ewé eleyii ti se ọkọ obì láti òrun
Ẹbọ ni awo pé kí ó ṣe...Kutukutu ni Ewé tii se ọkọ obì láti òrun


Taa ní jẹ gba ire ẹni lọwọ ẹni.Ifá dáadáa ni Ọsẹ méjì..

Sẹ́sẹ́ Olongo
Pìrì ẹ̀bìtì
Adifafun Orunmila baba yóó ma sowo...

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.

Post a Comment

Post a Comment