no fucking license
Bookmark

ORIKI ORI

Orí akèrègbè tóbi, ẹmu ni wọ́n fi ń dá,

Orí àdó kéré, àmọ́ ó yan iṣẹ́ ńlá.


Orí ẹni ni àwúre ẹni,


Orí ni à bá bọ, ká tó bọ̀'rìṣà


Orí mi gbé mi pàdé olóore, 


Orí mi wá jà fún mi,


Orí mi gbé mi débi gíga,


Orí mi gbè mí.

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.

Post a Comment

Post a Comment