IROSUN OGUNDA
Arufin Awo won Nile Alara
Aruda Awo ode oowo
Ijokun ofala ni sawo ile Alakole o balaya
Awon meteta ni won sefa fun olofin lagbo
oyinbo
Oji ekun Omo
Ekun iregbogbo ni sun
Nje Eduro efebo jumi Lara
Ijokun ofala
Eduro efebo jumi Lara
Eyin Arufin awo won nile alara
Eyin aruda awo ode owo Ijokun ofala ni n sawo ile Alakole obalaya Ijokun ofala
Eduro efebo jumi Lara
Ase Olodumare
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment