OBATALA has the authority to give Children according to Ifa
Indeed, in the odu Ogbedi IFA says that Obatala and Orunmila were chosen to receive the absolute authority to bless all barren women in the universe and bring to them the gift of children
Ogbedi says:
BI OJO IKU ABARAMEJI BA DARA LAYE
EHIN IWA WON KII SAN LORUN
LO DIFA FUN EJIOGBE ATI OBATALA
LOJO TI WON YOO NA ADO OMO BIBI
TI AWON ELEGUN WON YIO FI JEUN
OGBEDI NI GBOGBO ERAN ENI TI E BAJE
OTOTO ENIYAN NI YOO MAA DA
AWON LA FI TETE OHUN
KI A TO TORO OHUN LOWO ENI
A KII FI TULASI GBA NNKAN APO ENI WARA- WARA
LODIFA FUN OBATALA OSERE LASO (OSEERE MAGBO)
NIGBATI TI EDA YOO MAA RAWO – RASE
KI WON TO TORO OMO LOWO RE
AWON EDE NI EETISE
ORUNMILA NI A SE EYIN KO MO PE
OBATALA KII TA OMO RE LOPO
TRANSLATION:
IF THE DEATH OF PEOPLE WITH TWO PERSONALITY IS GOOD IN THE PHYSICAL WORLD
LIFE AFTER DEATH WILL BE WORSE IN THE HEAVEN
THIS THE IFA ORACLE DIVINED FOR EJIOGBE AND OBATALA
WHEN THEY WERE PLANNING TO HAVE A CHILD
WHEN THEIR FOLLOWERS WERE SEEKING FOR FOOD
OGBE-DI SAYS, ALL THE MEAT WE SHALL EAT
WILL BE GIVEN TO US BY DIFFERENT PEOPLE
THIS IS POWER OF WORD
BEFORE ASKING ANYTHING FROM OTHERS
NOBODY MUST USE FORCE TO TAKE WHAT DO NOT BELONG TO HIM
THIS ALSO DIVINE IFA FOR OBATALA OSEERE IGBO
WHEN THE PEOPLE ARE BEGGING HIM
FOR THE BLESSING OF THE WOMB
PEOPLE ARE ASKING WHAT CAUSE THE DELAY
ORUNMILA ANSWERED THEM
DID YOU NOT KNOW THAT OBATALA WILL NOT GIVE OUT HIS CHILDREN WITHOUT A COST?
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Related Post
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.