Ọfọ̀ ìdáàbòbò (Yoruba incantation for self-protection)
Ibi wọn rí o, kan kígbe àwa lọ
Orí kìí fọ́ ahun
Ẹ̀dọ̀ kìí dun ìgbín
Òtútù kìí mú ẹja lálẹ̀ odò
A kìí kí odidimọ̀dẹ̀ pé ó kú ìrọ́jú
Bí igi bá rorò, ó ní láti bá 'gbó gbé
Iwájú, iwájú ni ọ̀pá ẹ̀bìtì ńré sí
Àtẹ̀gbé lẹsẹ̀ n'tẹ̀nà...
~ KSA
Wherever they know they can broadcast our names
A tortoise does not suffer from a headache
A snail does not suffer from liver disease
A fish does not suffer from hypothermia
We do not say to the deaf and dumb, sorry
Even if a tree is terrible, it still has to coexist with other trees in the forest
A snare's pole always fall forward
A footprint on the road is final...
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment