Traditional Prayer Points For Children
Ọmọ ọwọ́ kìí kú lójú ọwọ́
Ọmọ ẹsẹ̀ kìí kú lójú ẹsẹ̀
Ọmọ Adanyin kìí kú lójú Adanyin.
Bí iná bá kú á fi érú bojú
Bí ọ̀gẹ̀dẹ̀ bá kú á fi ọmọ rẹ̀ rọ́pò
Ewé ní ń sin obì
The children of hands (fingers) do not die in the eyes of hands
The children of legs (toes) do not die in the eyes of legs
The children of Adanyin do not die in the eyes of Adanyin.
If fire is extinguished it replaces itself with ashes.
This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647) For spiritual guidance...We also sell spiritual product for wealth, protection and Open doors.
Post a Comment