Aayan Ogbufo
Ayan ogbufo ni sise itumo ede kan si omiran.
Ise ogbufo kuro ni gbefe, o gba ki a ni imo lori ede mejeji, itumo awon ona ede bi owe ati akanlo ede inu ede ti a fe tumo ati ede ti a fe tumo re si .
Ede Yoruba atata ati ilo amin ohun se Pataki ninu ise ogbufo alakoole.
AAYAN OGBUFO ELEYO ORO
Abandon ko sile
Abstain Fa seyin
Compare Fiwe
Deceit Etan
Education Imo-eko
Entertainment Idaraya
Home work Ise asetilewa
Overlap Wonu ara
Research Iwadi
Transfer Isinipo
Joke Apara
Wonder Iyanu
AAYAN OGBUFO ONIGBOLOHUN OWE ATI AKANLO EDE
All glitter are not gold |
Gbogbo ohun to n dan ko ni wura |
A tree does not make a forest |
Igi kan kii da igbo se |
Health is wealth |
Ilera loro |
He took to his heels |
O fie se fe |
Human confidence is vanity |
Igbekele eniyan asan ni |
A stich in time saves nine |
Kekere ni a ti n pecan iroko |
Hit the nail on the head |
So oju abe nikoo |
Bury the harchet |
Fiye denu. |
A stone heart |
Okan lile |
A tinkle of an eye |
Ni iseju aaya |
The child is the father of man |
Eyin ni di akuko |
AAYAN OGBUFO OLORO EWI
Ede Geesi
Ede Yoruba
On an evil day lojo buburu
The devil takes a drink of blood
Esu a mu eje
The battle is serious (oju) ogun le
The town is unhappy Gbogbo ilu gbekan
On an evil day Lojo buruku
A strong man cannot walk lonely in the road Alagbara ko le nikan rin
A terrible day makes a town desolate Ojo buruku ti I mu ilu di ahoro
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.