Apejuwe Awon Iro Faweli ede Yoruba
Gege bi a ti se mo wipe a le pim faweli Yoruba si ona meji: Aranmupe ati Airanmupe. O se Pataki lati ranti pe gbogbo faweli Yoruba ni atunyan ntori pe tan – an – na ona ofin maa n gbon bi a ba n pe won. Bi a ba fe se alaye faweli Yoruba Yoruba, a o tele awon ilana
a. Riranmu ati Airanmu
b. Giga ahon si aja enu
d. Ibi ti giga ahon nde
e. Irisi ete
e. Isesi ati ipo tan – an – na
a. Riranmu ati airanmu je ise afase. Bi afase ba faye sile fun eemi ti n bo lati odo ikun lati gba imu ati enu, iro ti a o pe yoo je aranmupe ( un, in, en, on, an) bi o ba je enu nikan ni eemi ngba, iro faweli airanmupe ni a o pe bi (I, e, a, u, o, e)
b. Giga enu si aja enu: Bi iwaju ahon ba gbera ahon lo kan aja enu, a o ma ape faweli iwaju (I, e, e, en, in) bi a ba si je pee yin ahon lo gbera gan – an; faweli eyin (o, o, u, on, un) aarin ahon ni faweli aarin (an, a)
d. Ibi ti ahon gade:- faweli ahonpe I & u. faweli ahandiepe (e ati o) faweli ayadiepe e ati o faweli ayanu pe (an, ati o)
e. irisi ete: roboto (o, u, un) tobi perese (a, I, an, in, an)
e. Tan – an –an ona ofun maa n gba nri nigba ti a ba n pe gbogbo awon iro faweli ede Yoruba. Idi niyi ti gbogbo awon fawli ede Yoruba fi je atunyan
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Related Post
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.