Aro Dida (Yoruba Dye Making)
Awon ohun elo fun aro dida niyi:
Omi-aluba, eeru soso-eyin, opolopo omi, ikoko arimole, ikoko kekeeke meji, opa-aro, aso funfun, elu, opon ti o fe ti eniyan le te aso le.
Ise obinrin ni ise yii bee si ni “aredu” je ikini fun awon alaro. Ise alaro ni ki o fi aro bu ewa kun aso nipa rire e sinu aro.
Die lara awon ilu ti aro dida ti wopo ni Ibadan, Oyo, Osogbo, Iseyin, Iwo, Ijebu, ati Abeokuta.
Bi aro ko ba mu aso mo, iru aro bee ti sa niyen. Eyi ni won n pe ni okusu aro.
Nigba yii, elu (coloring) ti won n lo ko ni wulo mo, won yoo da a nu; eyi ni won n pe ni sakiti.
Okusu aro (aro to ti sa) tun maa n wulo fun kikun ese-ile ti yoo si mu ki ese-ile bee maa dan gbinrin.
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.