AROKO AJEMO ISIPAYA
Aroko ajemo isipaya je aroko ti a fi n se isipaya awon ori oro to je mo ohun ayika eni.
Aroko yii fi ara jo aroko asapejuwe sugbono jinle ju u lo.
Bi aroko asapejuwe se le fi ki o sapejuwe ‘Ile-iwe re, aroko ajemo isipaya yoo fe ki a so nipa awon idagbasoke to de ba gbogbo nnkan ile iwe naa titi de ori isakoso.
Aroko ajemo isipaya maa n tu isu de idi ikoko ijinle itumo, anfaani ati aleebu ori oro.
Eyi nip e aroko ajemo isispaya pe kun imo to gbooro nipa sisafihan bi nnkan won se ri tabi sise.
Ki akekoo to le yege ninu aroko ajemo isipaya, o gbodo nifee si ise iwadii nipa nnkan ayika, ki o si maa ka orisirisi iwe, jona ati iwe iroyin ti yoo fun un ni imo kikan nipa nnkan ayika .
Aroko ajemo isipaya le je eleye-oro tabi apola ti won ni itumo to jinle.
Apeere aroko ajemo isipaya ni:
1. Omi
2. Iwe Iroyin
3. Ise Tisa
4. Oge Sise
5. Imototo
6. Aso ebi
Aroko ajemo isipaya tun le je or—oro bi
1. So awon nnkan ti iwo yoo se ti won ba yan o ni alamojuto eto iwasan ni agbegbe re.
2. Se ekunrere alaye bi iwo yoo se seto ayeye odun ibile laaarin awon akekoo ile-iwe re.
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.