Saturday, December 16, 2023

Aroko Alariyanjiyan

SHARE
Aroko AlariyanjiyanO se Pataki ki a mo wipe aroko ariyanjiyan gbodo tele akoko ode – oni. 


Ede tabi Yoruba ajumolo se Pataki ninu kiko aroko yii. Lilo awon ewa – ede bii owe, akanlo ede, afiwe ati bee lo se Pataki.     Aroko gbodo ni ilapa – ero, ninu ilapa ero ni a ti ri ifaara, koto inu aroko ati iwadii.Ninu iwadi ni a ti maa n saba fi ti ko oro gunle.     Aroko alariyanjiyan je ona ti a n gba gbe ero totun – tosi kale, tii a si wadi ero naa nipa fifi ero eni han lori koko ero bee. Ona meji ni a le gba gbe aroko yii kale.A le koko so ero wa si otun naa ki a to wa so si osi. Ni ona keji, a le so si otun, ki a tun so si osi. 


Ohun ti o se Pataki ninu aroko alariyanjiyan ni wi pe a ko gbodo dari apa kan fi kan sile.

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: