Aroko Asapejuwe

Aroko Asapejuwe 


Oruko mi ni AJE NLA bee ni mo si je omodekunrin lati ile adulawo, Afirika. Mo n gbe pelu baba mi, iya mi, awon aburo mi lokunrin ati lobinrin. Iyaaya mi ati iya-baba mi n gbe pelu wa bakan naa. Lai fa oro gun, ebi Ogbeni AJE NLA ko ju bayii lo.

A n gbe ninu ile ti baba mi ko. Eyi wa ni okan lara awon ileto ti eniyan le ba pade ni Iwo-Oorun Afirika.Emi ko ga pupo nitori pe mi ko ju omo odun mokanla pere lo. Awon aburo mi lokunrin ati lobinrin keere pelu. Amo awon obi mi ko reere lojo-ori. Ki gan-an lojo-ori won? Emi ko mo. Baba mi ti ju omo odun marundinlogoji sugbon o se e se ki iya mi je omo ogbon odun.

Ni idakeji ewe, awon obi ti o tuko obi mi wale aye ti di arugbo; won yoo ti pe omo aadorin odun. Amo n ko le fogun re gba ori.

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Post a Comment

Translate