Awe Gbolohun Afibo Ati Awe Gbolohun Asapejuwe

Awe Gbolohun Afibo Ati Awe Gbolohun AsapejuweAwe-gbolohun afibo ati Awe-gbolohun asapejuwe

A ti mo wi pe ni abo fun odindi gbolohun yala o le da duro tabi ko le da duro.

Bi a ba wo ibasepo to wa laarin awe-gbolohun afibo ati awe-gbolohun asapejuwe, a le fowo soya pe awe-gbolohun asapejuwe ni awe-gbolohun afibo ti o n sise eyan ninu gbolohun ede Yoruba.

Apeere:
Ajiboye gba pe ounje gidi ni iyan (awe-gbolohun afibo)
Ile ti Ade ko ti wo lana (awe-gbolohun asapejuwe).

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Post a Comment

Translate