Thursday, December 21, 2023

AWON ORISA ILE YORUBA

SHARE
ISORI EKO : AWON ORISA ILE YORUBAAwon Yoruba gba awon orisa bii asoju tabi iranse olodumare, alarina, lagata tabi alagbewi ni won je.

Ero awon Yoruba ni pe olorun feran awon orisa wonyi.

 

Okanlenirinwo ni awon orisa ile Yoruba . lara won ni Obatala, Orunmila, Esu, Sango, Ogun ati bee bee lo

 

Obatala ni awon Yoruba pe ni ALAMORERE. Won gbagbo pe oun ni o mo gbogbo eya ara eniyan ki olodumare to mi emi iye si inu won

Funfun  ni awon ohun elo obatala, lara won ni ileke funfun, aso funfun, bata funfun. Ounje ti o feran julo ni obe ate ( obe ti ko ni iyo ), igbin ati iyan.

Omi ajipon ni obatala maa n mu. Ko feran iwa aito bi iro pipa ati ole- jija. Ko feran elede, epo, emu, iyo, aja tabi omi ikasi

 

Orunmila ( IFA) ni olodumare fun ni ogbon, imo ati oye lati tun aye se. won gba pe o wa nibe nigba ti olodumare n se ipin ede. Idi niyi ti won fi n pe ni  Eleri-pin

 

Sango ti a tun n pe ni OLUFIRAN ti je oba alaafin oyo ri. Won gbagbo pe o ni ogun ati agbara lori ojo, ara ati imona mona. Bi sango ba n soro ina maa jade ni enu re. awon iyawo re ni OYA, OSUN ati OBA

 

Awon aworo re ni adosan ati elegun Sango. Awon olusin re maa n wo aso Osun ti sango feran nigba aye re,  won si maa mu Ose Sango lowo. O kunrin won  a maa di irun bi obinrin

Ounje ti sango feran ni amala pelu obe eweedu, eran agbo, orogbo ati obi. Idi niyi ti won fi n ki bayii :  sango oloju orogbo, Eleeke obi.

 

ESU ni olopaa tabi onibode. Gbogbo awon orisa ni won si beru re  yato si orunmila ti o je ore re. Esu lo maa ba awon orisa yooku wa ouje, to si n ba won be ebo. Gbogbo ebo to ba gbe lo maa n fin, Aarun-un si ni ipin tire ninu ebo ti o bar u.

Awon Yoruba n pe Esu ni ase buruku se-rere. Ibi idarudapo ni o maa wa bakan naa ni o maa fun awon olusin re ni omo ati owo.  Ita gbangba tabi enu odi ilu ni ojubo esu maa  n wa. Ere ti ipako re gun sobolo seyin ni amin idamo re.

Epo ni ounje ti Esu feran julo, eewo re si ni adi. Won maa n ki Esu bayi : Esu laalu Ogiri oko, A so irun waju po mo tipako……


This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: