Thursday, December 21, 2023

Didekun iwa ika Lawujo Yoruba

SHARE

DIDEKUN IWA IKA SI OMOLAKEJIIwa ika ni iwa buburu,iwa ti ko dara ti omo eniyan n hu si omolakeji.
Orisi iwa ika ti o wopo ni aye atijo
1.     Ikonileru

2.     Ifinisofa

3.     Fifi eniyan rubo

4.     Gbigbe ese le iyawo oniyawo

5.     Lile obinrin ni magun.

 

IWA IKA TI O WOPO LAYE ODE-ONI
1.     Jijinigbe

2.     Ipaniyan

3.     Lilo omo ni ilokulo

4.     Ifomosowo

5.     Lilu iyawo ile

6.     Ifapa bobirin lo

7.     Biba omode ni asepo

8.     Titan aarun kogbogun kale lona ti ko to

9.     Lilu omo ni ilukuluONA TI A FI LE GBA DIN IWA IKA KU LAWUJO1.     Gbigba alaafia laye nigba gbogbo

2.     Fifi ara eni si ipo enikeji ti a ba fe se ohun kan

3.     Fifi agbofinro mu awon iseka lawujo

4.     Fifi iya ti o to labe ofin je eni ti o ba huwa ika

5.     Iwaasu oro Olorun  ni awon ile ijosin gbogbo

6.   Tite agbalagba ti o ba ba omode ni ajosepo ni oda.

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: