ERE IDARAYA
Ere idaraya ni ere ti tewe-tagba maa n se leyin ise oojo won tabi ni akoko ti owo ba dile
Ere idara wa fun takotabo, omode-tagba. Orisirisi ere idaraya ati isori ni o wa
1.) ERE OSUPA: bojuboju, okun meran, eye meloo tonlogo waye
2.) ERE ABELE : ayo olopon
3.) ERE ITA GBANGBA : Arin, okoto , ijakadi, ere sisa, abbl
ERE IDARAYA ODE ONI
1.) ERE ORI PAPA : boolu afesegba ati afowogba, ere sisa, oniwon keke, ere asayi-papa-po , ere – gbagi , olopo-ibuso, abbl
2.) ERE ABELE : Dufaruti, kaadi, ludo .
ALEEBU ErE IDARAYA
1.) Ijakadi le je ki onkopa fi ara pa
2.) Elomiran le daku
3.) Okoto tita le da egbo si owo omo
4.) Iyepe le ta si omo loju ni idi ere aarin tita
5.) Bojuboju le je ki omo subu tabi ki o fese gun igi
ANFAANI ERE IDARAYA
1.) O MAA MU KI ARA OMODE JI PEPE
2.) Ayo tita maa muni lo oju bi o ti ye
3.) Bojuboju maa mu ki ara omode ya gaga
4.) O maa mu ewe gbagbe ise oojo
5.) O wa fun idaraya
6.) Ijakadi je ona ti a fi n ko ni igboya ati agbara
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.