Faweli Ede Yoruba

Faweli Ede YorubaOna meji ni ale pin iro ede oruba si:- Iro faweli ati Iro knosonanti. 

Awon iro faweli ni awon to je pe a maa n pe jade laisi idiwo fun eemi ti n ti nu edo foro bo.


 Ale pin iro faweli si ona meji. Faweli aranmupe ati faweli airanmupe. 


Awon iro faweli aranmu pe ni awon faweli ti o nilo eemi edo foro ati eemi  ti o n gba imu. 


Apere iro faweli aranmupe ni an, in, en, on, un

Awon faweli airanmupe ni awon faweli ti onilo eemi edo foro nikan lati pe won jade.


 Apere faweli airanmupe;- a, e, e, I, o, o, u.Awon faweli ede Yoruba le je faweli iwaju, aarin, tabi eyin; osi le je ahamipe, ahamidiepe, ayanupe, tabi ayanudiepe.

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Post a Comment

Translate