Gbolohun Onibo ati Awe gbolohun Afibo
Akiyesi ti fi han gbangba pe awon akekoo maa n gbe alaye oro mejeeji yii funra won. Eyi lo fa a ti a fi pinnu pe ki a to toka si ohun ti o mu gbolohun onibo yato si awe-gbolohun afibo, a oo koko ran a leti oriki gbolohun ati awe-gbolohun.
Ki ni gbolohun? Gholohun ni akojopo oro ti a n lo lati fi gbe ero okan jade ni ibamu pelu ofin isowo-lo-ede. Orisirisi ona ni a le gba pin gbolohun ede Yoruba nipa fifi oju ihun, ilo, tabi iye oro-ise wo o.
Ki ni awe-gbolohun? Eyi je okan lara koko oro ti a le ri fayo lati inu gbolohun olopo oro-ise. Ninu Gbolohun olopo oro-ise, a maa n ri olori awe-gbohun ati awe-gbolohun afarahe.
Ki ni Gbolohun Onibo? Eyi je okan lara awon gbolohun olopo oro-ise ti a fi gbolohun kan bo inu gbolohun miiran. A maa n lo awon atoka-afikun bi “pe”, “ki”, “lati” lati fi saaju gbolohun ti a fi bo inu gbolohun mii. Apeere: A gbagbo pe iku ni ere ese.
Ki ni Awe-gbolohun afibo? Eyi ni awe-gbolohun ti a fi bo inu gbolohun onibo nipa lilo awon atoka-afikun ti a menu ba ni isaaju. Apeere: …pe iku ni ere ese

Source of Article: https://www.orisa.com.ng

AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733

This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.

You can contact AJE NLA for ...

ODU OBATALA Consultation

Egbe Orun INITIATION

OSUN Initiation

Begging of the elders

Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.


Discover more from ORISA BLOG

Subscribe to get the latest posts sent to your email.

By AJE NLA

Leave a Reply

Translate »