Thursday, December 21, 2023

Igbeyawo ibile Nile Yoruba

SHARE

IGBEYAWO IBILE

 Asa Pataki ni asa igbeyawo  je ni igbesi  aye awon Yoruba, awon irufe igbeyawo aye atijo ni wonyi1.     FIFE NISU-LOKA

Igbeyawo ibile : Eyi ni igbeyawo  fife nisu lokoIGBESE IGBEYAWO IBILE1.)   IFOJUSODE : Bi omokunrun ba ti agba, awon obi tabi ebi re re yoo maa fi oju sode lati wa obinrin to dara fun un. Bi oun naa ba si ri eni to wu u, yoo fi to won leti.2.)   IWADI : Yoo se iwadii idile obinrin naa. ‘obi omokunrin yoo wa alaarina. Iyen eni ti mo awon obi omobinrin naa tiletile. Ise re ni lati wadi boya idile rere ni omobinrin naa ti wa.3.)   IJEHEN :  Alarina yoo seto bi omokunrin ati omobinrin yoo se ba ara won soro. Bi omokunrin ba ti ba omobinrin soro, ti omobinrin si ti gba , eyi ni Isihun tabi Ijehoo. Omokunrin yoo sanwo isihun. Ise alarina pari.4.)   ITORO : Obi omokunrin yoo lo toro omobinrin lowo awon molebi re ni owuro kutu.  Baale yoo sure fun omokunrin ati omobinrin ni oruko gbogbo ebi. Ojo yii ni obinrin ti di iyawo afesona. Awon asoju idile mejeji yoo si mu emu ati oti kii won to tuka.5.)   IDANA : Awon ebi oko yo sanwo idana, idile omokunrin yoo ru eru idana wa . apeere : Ogiju obi ajooopa, Ogoji Orogbo, Ogoji isu, Ataare Mewa  ati bee bee lo. Bi afesona  ba kere lojo ori, omobinrin yoo ma se ana titi omobinrin yoo fi dagba.  Ana-sise le je nipa reran baba iyawo lowo ni ise-oko. Ile kiko, ona yiye, ifowo-ran-ni-lowo. 6.)   IGBEYAWO : Ayeye ni ile oko ati iyawo, iyawo yoo maa paaro aso. Won yoo maa fun ni ebun, won yoo si maa gbadura fun un pe ile oko yoo san fun owo,fun omo.7.)   WIWE ESE IYAWO:  Enu ona abawole ni awon obinrin ile yoo ti pade iyawo. Won yoo bu omi si lese. Ami yii nip e o fi ese  ire wole oko. Iyale  iyawo yoo gbe iyawo wo ile. (I-GBE-IYAWO).IBALE : Bi oko ba ba iyawo nile, iyen ni pe iyawo yege, ibale ni apeere pe iyawo ko ti I ni ibasepo kan ri pelu okunrin. Oko re yoo paroko ranse si ana re pelu ekun akengbe emu ati owo ibale. Aabo agbe emu ni won yoo fi paroko si obi iyawo ti oko ko ba ba nile.

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: