IHUN ORO/SILEBU JSS2 (SECOND TERM )
SILEBU ni ege oro ti eemi lee gbe jade ni eekan soso.Silebu tun le je gige oro si wewe.
IHUN ORO: ihun oro ni ki a hun leta konsonanti ati leta faweli inu ede po di oro.
Orisirisi ona ni ihunoro tabi silebu lee gba waye ninu ede yoruba.Bi apeere:
1.Silebu/ihun oro lee waye gege bi faweli. O le je faweli airanmupe tabi faweli aranmupe.b.a:a,e,e,i,o,o,u,an,en,in,on,un.
2.Silebu/ihun oro tun le waye gege bi apapo konsonanti ati faweli. O le je faweli airanmupe tabi aranmupe
.Bi apeere : sun,lo, de, gbin, to,ke abbl.
3.Silebu/ihun oro le waye bii konsonanti aranmu asesilebu.N ATI M.b.a:oronbo,oronro,adebambo.abbl.
AWON BATANI IHUN ORO/SILEBU
Faweli-F = ka, ma,gbo,ran,sun, fe,lo, abbl.
Faweli ati konsonanti ati faweli-FKF = Aja, obe, Adan, Erin, Ife, Iku
Konsonanti ati faweli ati konsonanti ati faweli- KFKF = Baluwe, Salewa, Jagunjagun, Kabiesi
Konsonanti Aranmupe asesilebu – KF-N-KF = gogongo, gbangba, oronbo,konko,gbenga.
APEERE SILEBU
A/de
o/ba
ko/la/wo/le.abbl.
Ko / n / ko
gba / n /gba
ba / n/ba
du /n /du
O/ ro / n /bo
Oro olopo silebu – Oro kan le ni ju silebu kan le. Iru on bee ni a n rpe ni oro olopo silebu.
Bi apeere silebu ihun iye silebu owo ‘o’ __ mo f – kf meji
Ogede __ ‘o __ge __ de meta
Igbala __ i _gba _la meta
Oronbo __ O __ro _n _bo merin
ekunrere _ e _kun _ rere merin
Olopaa __ O _ lo _ pa _ a merin
Akiyesi pakati ti a se ni pe
1. konsonanti meji ko gbodo tele ara won ninu ede Yoruba
2. konsonanti ko le pari oro inu ede Yoruba.
A kii fi leta ‘U’ beere oro ninu ede Yoruba.
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.