Thursday, December 21, 2023

IHUN ORO/SILEBU

SHARE

IHUN ORO/SILEBU JSS2 (SECOND TERM )


        SILEBU ni ege oro ti eemi lee gbe jade ni eekan soso.Silebu tun le je gige oro si wewe.

        IHUN ORO: ihun oro ni ki a hun leta konsonanti ati leta faweli inu ede po di oro.

     Orisirisi ona ni ihunoro tabi silebu lee gba waye ninu ede yoruba.Bi apeere:

1.Silebu/ihun oro  lee waye gege bi  faweli. O le je faweli airanmupe tabi faweli      aranmupe.b.a:a,e,e,i,o,o,u,an,en,in,on,un.

2.Silebu/ihun oro tun le waye gege bi apapo konsonanti ati faweli. O le je faweli airanmupe tabi aranmupe

.Bi apeere : sun,lo, de, gbin, to,ke abbl.

3.Silebu/ihun oro  le waye bii konsonanti aranmu asesilebu.N ATI M.b.a:oronbo,oronro,adebambo.abbl.

                                            AWON BATANI IHUN ORO/SILEBU

Faweli-F = ka, ma,gbo,ran,sun, fe,lo, abbl.

Faweli ati konsonanti ati faweli-FKF = Aja, obe, Adan, Erin, Ife, Iku

Konsonanti ati faweli ati konsonanti ati faweli- KFKF =  Baluwe, Salewa, Jagunjagun, Kabiesi

Konsonanti Aranmupe asesilebu – KF-N-KF =   gogongo, gbangba, oronbo,konko,gbenga.

APEERE SILEBU

A/de

o/ba

ko/la/wo/le.abbl.

Ko / n / ko

 gba / n /gba      

 ba / n/ba     

  du /n /du   

O/ ro / n /bo

           

Oro olopo silebu – Oro kan le ni ju silebu kan le. Iru on bee ni a n rpe ni oro olopo silebu.

Bi apeere silebu ihun iye silebu owo ‘o’ __ mo f – kf meji

Ogede __ ‘o __ge __ de  meta

Igbala __ i _gba _la  meta

Oronbo __ O __ro _n _bo   merin

ekunrere _ e _kun _ rere  merin

Olopaa __ O _ lo _ pa _ a  merin

 

Akiyesi pakati ti a se ni pe

1.    konsonanti meji ko gbodo tele ara won ninu ede Yoruba

2.    konsonanti ko le pari oro inu ede Yoruba.

A kii fi leta ‘U’ beere oro ninu ede Yoruba. 

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: