Ise Abinibi Ati Ikini Lenu Ise Nile Yoruba
Awon Yoruba je iran kan ti o feran ise ati wipe ikini naa tun se Pataki, ko si ohun ti Yoruba kii se ikini le lori bi eniyan nsise, bi eniyan n se ohun ayo, bi eniyan n banuje awon Yoruba yoo ki iru eni bee afi ole nikan ni won maa n ki ni iki egan.
Eje ki a se ayewo awon orisi ikini lenu ise
ISE
IKINI
IDAHUN
1. Agbe
A-roko-bodun-de o
Ase o
2. Alagbede
Aroye o
Yo lu irin lati dahun
3. Ode
Arinpa Ogun o
Ogun yo gbe o
4.Onidiri
Ojugboro o
Iyemoja a gbe o
5. Alaro
Arepon
(yoo ni apasa lati fi dahun
6. Amokoko
Amoye o
Ase o
7. Atuko
Oko a re to o
Ase o
8. Babalawo
Aboru-boye o
A-boye-bo-sise
IGBELEWON
Se alaye orisiikini ti o mo fun awon akeko egbere
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Related Post
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.