Ise Abinibi Ati Ikini Lenu Ise Nile Yoruba

Ise Abinibi Ati Ikini Lenu Ise Nile Yoruba Awon Yoruba je iran kan ti o feran ise ati wipe ikini naa tun se Pataki, ko si ohun ti Yoruba kii se ikini le lori bi eniyan nsise, bi eniyan n se ohun ayo, bi eniyan n banuje awon Yoruba yoo ki iru eni bee afi ole nikan ni won maa n ki ni iki egan.Eje ki a se ayewo awon orisi ikini lenu iseISE

IKINI

IDAHUN


1.  Agbe

A-roko-bodun-de o

Ase o
2. Alagbede

Aroye o

Yo lu irin lati dahun
3. Ode

Arinpa Ogun o

Ogun yo gbe o
4.Onidiri

Ojugboro o

Iyemoja a gbe o
5. Alaro

Arepon

(yoo ni apasa lati fi dahun
6. Amokoko

Amoye o

Ase o

7. Atuko

Oko a re to o

Ase o
8. Babalawo

Aboru-boye o

A-boye-bo-sise


IGBELEWON

Se alaye orisiikini ti o mo fun awon akeko egbere

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Post a Comment

Translate