Isinku Nile Yoruba 
Kari aye ni oro iku; bee si ni oje ase Eledumare fun gbogbo ohun ti o da, ko si eniyan ti o mo iru iku ti yoo pa ohun tabi ibi ti iru iku bee yoo ti wa. 
ilana oku sisin maa nje mo asa tabi eesin. Awon eya kan maa n sun oku nina sugbon Yoruba gbagbo wipe irin ajo ni iku bi won ko ba si fun oku ni isinku to tona, iru oku bee le ba idiwo pade.
Orisi oriki ni awon agba igbaani fun iku;
1.     Iku pa babalawo bi eni ti ko gbofa
2.     Iku ti fole adun
Yoruba pin oku si ona meta:-
i.                    Oku agba
ii.                  Oku ofo
iii.                Oku abami
Bi eniyan ba dagba to dogbo ki o to ku, iru oku bee ni Yoruba npe ni oku agba. Bi omde tabi eniyan ti ko darugbo tabi gbaye sohun rere, iru oku bee ni Yoruba maa n pe ni oku ofo.
Oku abami ni oku awon to Yoruba gbagbo wi pe abami eda niwon tabi eyan to ba ku lona meeriiri fun apere, eniyan ti oku sodo, eniyan ti sanponna pa, obinrin ti oku pelu oyun ninu, eniyan ti opokunso, enitan ti ara san pa, oku afin, oku adete, oku abuke, abbl. Yoruba ni orisirisi ilana ti won maa n gba sin iru awon oku bawonyi.

Source of Article: https://www.orisa.com.ng

AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733

This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.

You can contact AJE NLA for ...

ODU OBATALA Consultation

Egbe Orun INITIATION

OSUN Initiation

Begging of the elders

Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.


Discover more from ORISA BLOG

Subscribe to get the latest posts sent to your email.

By AJE NLA

Leave a Reply

Translate »