Thursday, December 21, 2023

Isomoloruko ATI Ohun ELO isomoloruko

SHARE

Bi awon Yoruba se ka omo bibe si naa ni won ka isomoloruko si. Isomoloruko je ohun ariya ati ayeye. Awon oruko ti a maa pe omo saaju ojo isomoloruko ni wonyi :  Ikoko, Tunfulu, Arobo, Alejo Okan ninu agba obinrin ile yoo ti fa irun ori ikoko, won yoo wo aso fun un. Iyale ile tabi agba okunrin  ni n seto isomoloruko.Owuro kutu tabi owo iyaleta ni won n so omo loruko. Ojo keje ni a saaba n so omobinrin ni oruko, ojo kesan-an ni omokunrin, ti ibeji si je ojo kejo Won dupe lowo olorun fun ebun nla ti o fun idile naa, bakan naa ni won yoo juba baba-nla omo.Leyin eto yii ni won yoo ko eroja isomoloruko si ori tabili ni oju agbo. Iyale ile tabi bale to n dari eto yoo kede oruko  ati itumo won ni kookan, awon ebi yoo si maa so owo si inu omi, leyin ni adari eto yoo maa fi awon eroja isomoloruko ni okookan  bee ni yoo si maa fi se adura fun omo.

 

 

 

AWON OHUN ELO ISOMOLORUKO

  1. Omi – Itura aye : omo naa ko ni ri inira
  2. Ataare – Opo omo tabi asepe oore : ki omo naa di iru , ki o di igba
  3. Orogbo – Emi gigun : omo naa yoo dagba , yo dogbo
  4. Obi – Emi gigun : obi ni bi iku, obi ni bi arun, omo naa ko ni ku ni rewerewe 
  5. Oyin , Aadun, Ireke, Iyo – Igbadun : ki aye omo naa kii o dun
  6. Oti -  Ajinde ara : oti kii ti, oti kii sa, aye omo naa ko ni ti
  7. Epo – Ero : ki aye omo naa ki o ri irorun
  8. Eku/Eja – jije aye pe ati lila isoro : isoro ko ni bori omo naa
  9. Owo  - Riri owo na : omo naa yo ri owo fi s’aye

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: