Saturday, December 16, 2023

Itoju Ara Ati Ayika Nile Yoruba

SHARE
Itoju Ara Ati Ayika Nile Yoruba 
Lati le dena arun ati aisan ni imototo fi se Pataki. Ona ti a si n gba ni imototo ni ki a se itoju ara ati ayika.

1.       Iwe wiwe wa lara ipa ti eniyan maa n ko lati toju ara. Ki a fi ose ati kan-in-kan-in ti o dara pelu girisi (ipara) fun ara ni ewa ti o ye.

2.       Eyin fifo se Pataki fun enikeni to ba few a ni imototo. Eyi se Pataki loorekoore nigba ti eniyan ba ji lowuro ati nigba ti eniyan ba fe lo sun. Burosi tabi pako irunyin ni a fi n foe yin mo.

3.       Itoju irun-ori ti wa lati igba laelae titi di oni; tokunrin tobinrin lo si maa n toju irun. Awon obinrin gbodo se irun ni kiko tabi ni didi nigba ti awon obinrin maa n ge irun won . O tun je kannpa lati maa fi omi ati ose fo irun wa.

4.       Itoju eekanna owo ati eekanna ese nipa ki a maa ge won, ki a si maa fo won lati dekun idoti to fe tabi to le farapamo sisun awon eekanna wa.

5.       Itoju aso o gbeyin ninu akitiyan lati dena arun to le kolu ara nipa ki eniyan ma wa ni imototo. Nse ni a gbodo maa fo awon aso wa pelu ose ati omi to mo.

6.       Itoju ayika (yala_ ile-igbe, ile-eko, ile-ise, tabi oja) se Pataki bakan naa. Eyi ni ko ni je ki eniyan je oye adara-lode-ma-dara-nile tabi adara-nile-ma-dara-lode.


 Lojoojumo ni o ye ki a maa fi igbale gba gbogbo ayika wa. A sit un gbodo maa gbon gbogbo panti ati jankariwo to so mo ile. 


A gbodo sa gbogbo agolo, igo-afoku, ewe ati ora tabi ohunkohun to le ko ijamba ba eniyan. 


A gbodo maa gba, ki a si tun maa fo oju gota ati oju-ona agbara, ki a si tun di awon ibi ti salanga ba ti fo lati dena arun ti eniyan le ko lati ipase oorun buruku. 


A gbodo maa se itoju ti o ye fun awon ile-iwe, ile-igbonse ati ati ayika idana. A gbodo maa ro awon oko ayika, ki a sit un ko gbogbo ohun ti ejo, efon, akeekee ati eku le farapamo si se eniyan ni ijamba jina si ayika ileegbe.

Ise imototo ko yo enikeni sile; ijoba, elegbejegbe,odo adugbo nitori pe agbajowo ni a fi n soya.

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: