Monday, December 11, 2023

IWULO EPO OBO FUN IWOSAN (Uses of Epo OBO for various sickness )

SHARE
IWULO EPO OBO FUN IWOSAN (Uses of Epo OBO for various sickness )



1. Ao lo enpo obo ti yio kunna. Ao da sinu omi toba loworo (togbona
die) lowuro kutukutu. Ao fi we pelu ose tobawu wa (ki owo aje ma
tewa).


2. Enpo obo lilo, pelu iyo ati eru inu aro, ao po mo ose, ao ma fi we
(arobi).


3. Enpo obo, ao jo pelu odidi atare 1, ti oba ti fe jo tan, ao ju ori sinu
agbadana, ao lo, ao ma fi foko mu lalale (eyonu).



4. Ao gba epo pupa lori ina, tio ba ti gbona dada, ao da enpo obo ti ati
losi, ao farabale kogbona dada, ao yo epo na, enpo obo to wa ni be
ao po mose ao ma fi we, ao si ma la epo na...(eyonu).



5. Enpo obo, ata ijosi 9, ao gun po mo ose dudu, ao ma fi we fun jo
meta meta...(fun ibere ontoruwaloju).



6. Igbe adie ati enpo obo pelu atare, ao jo po, ao po man ori. ao ma ju
sinu

eko gbona lararo (ebe awon agba).



7. Ao gba enpo obo ninu epo pupa, ao da epo pupa na sinu mis paris,
holy mikel, bintu, eyokookan, ao ma fi para, enpo obo toku ni isale
kokona, ao po mo ose, ao ma fi we (fun eyonu awon agba).

This Article is written by AJE NLA (whatsapp +2347031178647).For the following:::

IFA consultation and Divination

Egbe Orun initiation

Appeasement of Egbe Orun

Yes and No questions

Feeding of Ori (inner head)

Feeding of ORISA

IFA INITIATION

Solutions to Problems

Source: https://www.orisa.com.ng

SHARE

Author: verified_user

AJE NLA Spiritual Traveller | OLOBATALA | OMO OLOKUN, OMO ORISA | BABALAWO OMO ORUNMILA | CEO www.orisa.com.ng | +2347031178647 For IFA Consultation, Divination, Yes / No questions , spiritual guidance, Dream interpretation etc whatsapp https://wa.me/2347031178647

0 $type={blogger}: