Yorùbá bò Wón ní, ‘a so Omo ní sódé, Omo lo àjò Ó dé, a so Omo ní sóbò, Omo ràjò ó bò, a wá so Omo ní Sórìnlo, omo ràjò kò dé, ta ni kò mò pé Ilé ni omo ti mú orúko anù lo? Ní tòótó ni wí pé orúko Omo níí ro omo, orúko ęní sì ní ìjánu ęní.
Jíjé orúko tó ní ìtumò jé ohun tí ìran Yorùbá káràmáàsíkí púpò, won kan kìí sàdédé fún Omo lórúko.
 Ní ilè Yorùbá àwon ìsèlè tó bá selè lásìkò tí Wón bímo tàbí ohun tó bá rò mó bí Omo se wáyé lásìkò ìbímo ni wón wò kó tóó so Omo lórúko.
 Ìdí nìyìí tí Yorùbá fi wí pé ‘òòró Ilé, ibú Ilé, làá wò ká tóó somo lórúko.
 Ìyí túmó sí wí pé kò sí orúko tí kò ní ìtumò nílé Yorùbá.
A ó ma tè síwájú lósè tí ń bò.

Source of Article: https://www.orisa.com.ng

AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733

This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.

You can contact AJE NLA for ...

ODU OBATALA Consultation

Egbe Orun INITIATION

OSUN Initiation

Begging of the elders

Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.


Discover more from ORISA BLOG

Subscribe to get the latest posts sent to your email.

By AJE NLA

Leave a Reply

Translate »