Ogbè Òfún Méjì,
Ifá says:
Àjìtú gb’ayé
Arìngìnnìgìnì gba’yì
Ò jí ní kùtùkùtù r’óhun ọrọ̀ ṣ’àrí gbọ̀n lọ ọ̀run
Díá fún Ọ̀rúnmìlà
Baba ńt’ọ̀run bọ̀ wá’yé
Díá fún Ọmọ ènìyàn
Wọ́ n maa pín sí èrò mẹ́ ta l’áyé
Àwọn tí wọ́ n wá ṣ’ayé
Àwọn tí wọ́ n sìn wọ́ n wá’yé
Àwọn tí wọ́ n yà wá wò’ran l’áyé
Gbogbo wọn ́nbọ̀ wá ṣe ohun mẹ́ ta l’áyé
Wọ́ n ńbọ̀ wá hù’wà ire
Wọ́ n ńbọ̀ wá hù’wà ibi
Wọ́ n ńbọ̀ wá hù’wà ṣe kò-ṣe’bi-kò-ṣe’re
Àti ohun mẹ́ ta sílé ayé lẹ́ ẹ̀kanṣoṣo?
Ó ní a kìí dá akọni mẹ́ta sílé ayé
Kí wọ́n má fi apá gún ara wọn
Nítorí bí aga bá f’aga gbá’ga
Ọ̀kan á tẹ̀
Olódùmarè ní òun fẹ́ mọ bí’nú ọmọ aráyé ti rí ni
Àásẹ̀ẹ́mọ̀gàmọ̀gà kìí rí ohun ọrọ̀ ṣe àrígbọ̀nlọ Díá fún Àgbọnnìrègún
Ó ń ti Ìkọ̀lé Ayé lọ sí Ìkọ̀lé Ọ̀run
Ó ń lọ sọ́dọ̀ Olódùmarè lọ béèrè ọ̀rọ̀
È é ti rí tí Olódùmarè fi dá èrò mẹ́ta
Source of Article: https://www.orisa.com.ng
AJE NLA the son of OBATALA is registered with CAC No: 8022733
This Article was written by AJE NLA the son of OBATALA with +2347031178647.
You can contact AJE NLA for ...
ODU OBATALA Consultation
Egbe Orun INITIATION
OSUN Initiation
Begging of the elders
Feeding of ORISA OSUN, OBATALA, Egbe Orun, TAJENIKARO (AJE that fights for your wealth), AJELETI (AJE from IYAAMI), ONIMERE (for all Emere), AJASORO (Revenge and door opener), AJE OLOKUN, ESU, ELEGBA (Justice and way opener) etc.
Discover more from ORISA BLOG
Subscribe to get the latest posts sent to your email.